Welcome International Students

中文 Deutsch Èdèe Yorùbá EnglishFrançais日本語
한국어PortuguêsPусскийEspañolSvenskaInternational Students

Eya ikeko fun asa lati orile agbaye ti ile eko Gustavus Adolphus ki gbogbo yin ti ewa ni ibi ni ojo oni. Ase tan lati ri wipe awon akeko lati orile agbaye ri iranwo to joju lati pari eko won. A o se akitiyan ati iranwo lati ri wipe gbogbo igbese lati bere eko, yan ise itanna ati
lati pari eko ni gbogbo akeko ri gba lati owo wa ati bebe lo. Awon oluko ti ojoju tio si muna ni owa ni ile eko Gustavus Adolphus, won si se tan lati sise po pelu awon akeko lati ri wipe won yege ninu eko won. Ile eko wa je ibi ti abo ati ife po ti asi nlo po pelu ife. Apejo eyin akeko lati orile agbaye se pataki si ile eko yi, papa ju lo asa, imo ati oye
ti e o fi kun eyi ti oti wa ni ile ni ile eko Gustavus Adolphus. Enikeni ti o ba ni ibere tabi ti ofe iranwo ki olo si ori ero computer, ati se orisirisi
itanna lati se alaye tabi da yin lohun opolopo ibere ti e le ni fun eya ti on gba akeko wole ni ile eko. Ti e ba si fe ele wa ba wa fun ibere ti e ba ni.

Admissions Office

contact us if you have any questions.